Asake

2:30

in 2:30

Leggi il Testo,la Traduzione in Italiano, scopri il Significato e guarda il Video musicale di 2:30 di Asake contenuta nell'album 2:30. “2:30” è una canzone di Asake. 2:30 Lyrics.

TESTO - Asake - 2:30

VIDEO MUSICALE

TESTO - Asake - 2:30

Uh
Obah
What demma say?
Obah
Run
Hmm, hmm, hmm, hmm
Hmm, hmm, hmm, hmm
Hmm, hmm, hmm, hmm
Hmm, hmm, hmm, hmm


Awa de, awa de de
Awa lọmọ to n sọ ti o seke, ye
Orimọlade gbemi debẹ
Jigan jigan
Ẹsẹ mi o delẹ, delẹ

Alaye mi stop shebẹ
O fẹ jenbi, otun fẹ jenbẹ
Opọ se
Agbawo, fẹnu fo fence

Sun sẹ yin
Amọrawa, sho get?
Abinibi yato s'ability

Ẹsọ fun wọn tan ba teri si
Wọn ma pa lori
Tẹnu kọ, emi promising
Awọn tẹ fọ fun, fọ fun mi
Tori ko sẹ lomi

Many many fẹ dabi mi
Eri bi
Ẹgbọlorun tobi
Mo da aso-ẹbi for my country

You can call me Mr Money

Hmm, hmm, hmm, hmm
Hmm, hmm, hmm, hmm
2:30 fẹlu
Oya ka turn up
Kilẹ to mọ

Hmm, hmm, hmm, hmm
Hmm, hmm, hmm, hmm
Ye, ye, ye
2:30 fẹlu (Thirty fẹlu)
Oya ka turn up
Kilẹ to mọ

Ere moba wa kosi ja

Shokoto pen pe, ye
Ayenika, yebo, yeba

Formation logba, ye ja
Ọmọ'yami ko stay wise
Tranquility, tranquility
I no get time to dey form activity
Kole kalas, I dey find stability
Like abacha, money long infinity

What's the chances?
What's the probability?
To see a better version of me with agility
No you can't fake reality
Ogun, principality and calamity
Mo ti lọ, mo ti pa iyen ti
Bẹbẹ no de for jiji
O shi wa n titi
Still get money like Fifty

Dripping like Fiji

I be real G

Hmm, hmm, hmm, hmm
Hmm, hmm, hmm, hmm
2:30 fẹlu
Oya ka turn up
Kilẹ to mọ

Hmm, hmm, hmm, hmm
Hmm, hmm, hmm, hmm
Ye, ye, ye
2:30 fẹlu
Oya ka turn up
Kilẹ to mọ

Vai alla Traduzione

CONDIVIDI STORIES

Crea gratuitamente un'immagine con i tuoi versi preferiti pronta per essere condivisa nelle tue storie social.
Vuoi inserire un nuovo brano? Inviaci il testo!

Questo testo ha informazioni mancanti? Contattaci Ora!